
ÌPÌLẸ̀ IṢẸ́ 1.0 Ìfáárà Fíìmù jẹ́ ọ̀kan gbòógì lára àwợn iṣẹ́-ọnà tí à ń lò láti fi àṣà àti ìgbàgbọ́ Yorùbá hàn. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ Yorùbá ni kò mọ àṣà àti ìgbàgbọ́ Yorùbá tí wọ́n sì tipa bẹ́ẹ̀ sọ àmì ìdánimọ̀ wọn nù. Àkíyèsí fi hàn pé, ọ̀pọ̀ òṣèré ni wọ́n máa ń ṣe ìgbélárugẹ àṣà […]
Source
from EDUPEDIA247https://ift.tt/30tcCoD
via
EDUPEDIA
Comments
Post a Comment